OLOLUFE IWO LOKAN MI YAN
Chorus
Ololufe iwo lokan mi yan
Iwo ni ma balo , titi ojo aye mi
Ololufe onitemi
Iwo ni ma balo titi ojo aye mi
Verse 1
Iwo ni mo fe, iwo lonitemi
Ade ori mi,oko mi
I call you my ancient of days
I call you the lord of my life
Mofe ba o lo, together forever
Verse 2
Kosohun tole yawa, moti sepinu, lokan mi,
lati mase feere,onitemi ololajulo
Mofe baolo,iwo ni mo feran julo,
mase fimisile lo olufemi owon
Verse 3
Mafimisile lo, mofe fi iwa jo e baba
Tori enibini lanjo, je kin fi wa jo o
Mope o Larugbo ojo, Adagba ma paro oye
Iwo leni Mimo ti ‘n se Mimo, ti ‘n je Mimo
Ti ‘n gbe bi mimo